Darapo mo Societas Linguistica Europaea

Gegebi omo egbe, o ni anfani lati gba awon iwe atejade imo ijinle ede aye mooka Folia Linguistica ati Folia Linguistica Historica ni odoodun.

Imo siwaju sii Idarapo mo egbe lori ero ayelujara

Awon ti won ti je omo egbe

Awon omo egbe ni anfani nipase ero ayelujara lati lo si SLE Members’ Area lati paaro adiresi eyi ti won fi sile tele, ati lati tun iwe omo egbe odoodun won se yala lori ero ayelujara tabi nipa fi fi owo si iwe omo egbe.

Societas Linguistica Europaea meeting

The 57th Annual Meeting

Time:

21 to 24 August, 2024

Place:

University of Helsinki, Helsinki, Finland

Organizer:

Prof. Dr. Matti Miestamo