Societas Linguistica Europaea
Societas Linguistica Europaea (SLE) je egbe ti a da sile ni iha ilu oyinbo lati sise lori imo ijinle ede ati lati gbe ede laruge ni gbogbo ona. Awon omo egbe le je alawo funfun tabi ki won wa lati iha ibomiran ni agbaye.
Darapo mo Societas Linguistica Europaea
Gegebi omo egbe, o ni anfani lati gba awon iwe atejade imo ijinle ede aye mooka Folia Linguistica ati Folia Linguistica Historica ni odoodun.
Imo siwaju sii Idarapo mo egbe lori ero ayelujaraAwon ti won ti je omo egbe
Awon omo egbe ni anfani nipase ero ayelujara lati lo si SLE Members’ Area lati paaro adiresi eyi ti won fi sile tele, ati lati tun iwe omo egbe odoodun won se yala lori ero ayelujara tabi nipa fi fi owo si iwe omo egbe.